Covid-19 nípìnlẹ̀ Ọ̀yọ́ rárí wọ Ògbómọ̀ṣọ́Fẹ́mi Akínṣọlá

Ìtànkálẹ̀ àrùn apinni léèmí Covid-19 ti tàn ràn mọọ bíi iná  pápá kọja Ibadan, wọ ìlú Ògbómọ̀ṣọ́.

Gómìnà Ṣèyí Mákindé nínú ìkéde kan tó fi síta lójú òpó abẹ́yefò rẹ̀ lọ́jọ́ Ẹtì sọ pé, méjì lára àwọn ènìyàn mẹ́jọ tó ṣẹṣẹ ní àrùn náà, ló wá láti ìlú Ògbómọ̀ṣọ́,awọn mẹ́fà yókù jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Togo

 Gómìnà ṣàfikún ẹ̀ pé èsì àyẹ̀wò méjì míràn tó jáde ní alẹ́ ọjọ́ Ẹtì fihàn pé dókítà kan níléèwòsàn UCH n’Ìbàdàn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé láti ìlú Kano, tí ẹnìkejì sí jẹ́ òṣìṣẹ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ DSS.

Lọ́wọ́lọ́wọ́, ènìyàn ogún ló ń gba ìtọ́jú fún àrùn apinni léèmí  Covid-19 nípìńlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Comments

Popular posts from this blog

Ekiti: Governor Responds To Claims Of Selling State Lodge ln Abuja

"President Buhari Trusts Women More Than Men" - Garba Shehu

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ẹ̀yin lẹ ránmi níṣẹ́, n ò níí fojú u yín gbolẹ̀--Ṣèyí Mákindé