Akẹkọo ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ yóó wọlé l'oṣù keje ọdún yii -- MakindeFẹ́mi Akínṣọlá

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé tí ṣọ ọ́ pé bí àfojúsùn ìjọba, ò bá  yẹ̀, o yẹ kí àwọn akẹ́kọ́ọ̀ ìpínlẹ̀ náà ó lè padà ṣẹ́nu ètò ẹ̀kọ́ ọ wọn nínú oṣù keje ọdún yii. July 15, 2020.

Ọ̀rọ̀ yìí ní Gómìnà ṣọ  lọ́jọ́ Ẹtì ,ní Hẹ́díkọtà àwọn òṣìṣẹ́ náà tó kalẹ̀ sí ldi - Ape lbadan, níbi ètò àkànṣe kan tí wọ́n fi s'órí  àyájọ́ ọjọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́dọdún, tó  kò .

Gómìnà ní ìjọba tí bá àwọn olùdásílẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ aládáni ṣọ̀rọ̀ lórí bí wọ́n se gbé àwọn ilé ẹ̀kọ́ gbogbo tí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
Ó ní, bí ilé ẹ̀kọ́ gbogbo se di àgbétì yìí, àwọn ilé ẹ̀kọ́ aládáni ti mọ̀ ọ lára torí pé, àwọn akẹ́kọ́ọ̀ tó yẹ kí wọ́n sanwo wà nínú oludé àpàpàdodo.
Gómìnà ní àwọn olùdásílẹ̀ yìí gba olùkọ́ tó ń kọ àwọn ọmọ àti pé owó  tó bá tọwọ́ àwọn òbí wọn wá ní wọ́n fi ń sanwó olùkọ́.

Ó ní bí nǹkan se wá rí yìí, kí àwọn òbí rí àsìkò yìí bí oludé gbọọrọ, bí wọn bá tí wá wọlé, kò ní sí oludé kankan mọ́, ọsẹ méjì ní wọ́n yóó ló láti parí ètò ẹ̀kọ́ sáà kejì,ti sáà kẹta o sí bẹrẹ láì sí oludé.

Gómìnà ní bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àsìkò yìí le díẹ̀ pẹ̀lú làlúrí tó dé bá  ọrọ̀  ajé ìlú, síbẹ̀, òun o gbìyànjú dúró lórí ìpinnu òun lójúpò ìlérí tí òun se lásìkò ìpolongo ìbò pé òun ó máa san owó

 oṣù ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n oṣù èyí tí wọ́n ṣọ di ọjọ́ GSM.

Comments

Popular posts from this blog

Ayade, The Cry Cry Baby In Peregrino House By AGBA JALINGO

FAYEMI CONGRATULATES EX-DEPUTY GOVERNOR, ADELABU ON 70TH BIRTHDAY

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀