Posts

Showing posts from April, 2020

Ekiti Assembly Resumes Next Monday

Image
Ekiti State House of Assembly has announced the decision to resume her legislative activities on Monday 4th, 2020, after weeks of indefinite suspension.

In a statement by the Chairman, House Committee on Media and Publicity, Hon. Yemisi Ayokunle, confirmed the decision of the House to resume Plenary after weeks of lockdown to curtail the spread of the Covid-19 pandemic. The resumption is without prejudice to all the established protocols of prevention of the Virus.

She affirmed  that a good part of the House's meetings will be virtual conferencing.

The statement also stated that the resumption goes in line with the State Government's directive,  indicating  Public Servants on grade level 13 above and those offering essential  services in the State to resume on the said date.

Hon. Ayokunle stressed that the opportunity would afford the Lawmakers to attend to all critical legislative assignments in waiting, and to complement Government's effort to making the State safe.

She…

FOUNTAIN NEWSBREAKER'S AWARENESS CAMPAIGN ON COVID-19

Image
Frequently Asked Questions on Coronavirus

What is COVID-19?

Coronaviruses are zoonotic, meaning they are normally transmitted between animals and people. The COVID-19 is a disease caused by a new strain of coronavirus that has not been previously identified in humans. It was first reported to WHO on the 31st of December, 2019 in Wuhan, China
 What is the source of COVID-19?

Scientists and public health officials are working hard to identify the source of the SARS-CoV-2 which is the virus that causes COVID-19. The initial transmission appeared to be from an animal source, but there has been person-to-person transmission in countries.

The virus can spread from one person to another, most likely through droplets of saliva or mucus

Has anyone in Nigeria gotten infected?

Yes. The first case in Nigeria was confirmed on Friday, February 27, 2020 in Lagos in a business Italian traveller who arrived Nigeria on February 25, 2020 and became symptomatic on February 26, 2020. Contact tracing is o…

Buhari Salaye Oun ti yio fi ọgbọ̀n bílíọ̀nù dọ́là owóyàá àjọ IMF ṣe

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Ijọba àpapọ̀ ti ṣàlàyé pe, oun fẹ́ gba owó lowo ajo IMF láti  mú kí ọrọ̀ ajé  Nàìjíríà gbéra lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí Covid-19 yìí, nitori pe epo rọ̀bì kò tà mọ́ ní ọjà àgbáyé, bee si ni ọ̀rọ̀ ajé àgbáyé ti dẹnu kọlẹ̀.

Ìjọba ní owó náà ni òun fẹ́ fi ṣe àwọn àkànṣe iṣẹ́ tó yà kalẹ̀ nínú ètò ìṣúná ọdún 2020.

Ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun nílé aṣòfin àpapọ̀ ilẹ̀ wa fi  òǹtẹ̀ lu ọgbọ̀n bílíọ̀nù dọ́là ($30bn) owó tí Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ wá fẹ́ gbà lọ́dọ̀ àjọ ayánilówó lágbàáyé IMF.

Láti ìgbà tí ìjọba àpapọ̀ sì ti tẹ́ pẹpẹ owóyàá náà síwájú àwọn aṣòfin àgbà, làwọn ọmọ orílẹ̀ èdè yìí tí ń béèrè pé, ṣé ilẹ̀ wá tún nílò owóyàá kankan lásìkò tí ọrọ̀ ajé àgbáyé ti dagun yìí?

Wọ́n ní ṣé àkọ̀tun ìbéèrè fún owóyàá yìí, èyí tí yóò mú kí gbèsè tí ilẹ̀ wá jẹ láwùjọ àgbáyé fò fẹ̀rẹ̀ sì bílíọ̀nù mẹ́tàdínlọ́gọ́rùn ($97bn), kò ní ṣe àkóbá ńlá fún ìgbáyé-gbádùn àti ọjọ́ ọ̀la àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè yìí?

Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo, Òǹdó lọ́wọ́--INEC

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s'ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ  ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò  Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò dí àwọn lọ́wọ́ rárá láti múra sílẹ̀ de àṣeyọrí ètò ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àti Ẹdó.

Wọ́n ní kò sí ayípadà kankan lórí àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ ní gbígbé láti ṣètò ìdìbò gómìnà àti àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn ìpínlẹ̀ méjéèjì náà..

Ìpínlẹ̀ Edó wà ní Gúúsù Gúúsù Nàìjíríà nígbà tí ìpínlẹ̀ Òǹdó wà ní ìwọ̀ oòrùn Gúúsù Orílẹ̀ yìí.

KANO STATE RECEIVES 110 TRUCKS OF PALLIATIVES RICE, GRAINS FROM FG

Image
The Federal Government has sent 110 trucks of palliatives foodstuff to the Kano State Government through the Federal Ministry of Humanitarian Affairs, Disaster Management and Social Development. for distribution to the needy, vulnerable and people of concern in the state. Minister of Humanitarian Affairs, Disaster Management and Social Development, Sadiya Umar Farouq, said that the Ministry delivered ten trailer-loads of parboiled rice to the state government about two weeks ago, and also directed the National Emergency Management Agency (NEMA) to deliver 100 trucks of grains to five locations in Kano State for distribution to poor and vulnerable households on the instruction of President Muhammadu Buhari.
The grains in 100 trailers comprise millet, sorghum and maize, which were released from silos holding the country's strategic food reserve located across the country. 
It could be recalled that President Muhammadu Buhari has directed the Federal Ministry of Agriculture and Rural D…

Ikú di tọ́rọ́ fọ́nkálé nílùú Kano

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá


Yorùbá bọ̀ wọ́n ní ọwọ́ tó bá ń duni, ẹnìkan kìí kí b'abẹ́ àgbádá ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí o, bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje ti múgbe bọnu pé ìjọba àpapọ̀ gan an lọ́wọ́ sí bí wàhálà àrùn apinni léèmí Coronavirus ṣe ń gogò síi ní ìpínlẹ̀ náà.

Gómìnà Ganduje ní ń ṣe ni ikọ̀ amúṣẹ́yá ti Ìjọba àpapọ̀ gbé kalẹ̀ lórí gbígbógun ti àrùn apinni léèmí Coronavirus lórílẹ̀-èdè- Nàìjíríà, ,dẹ́yẹsí ìpínlẹ̀ Kano lásìkò tí àrùn náà búrẹ́kẹ́ sí i  báyìí.

Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò  kan tó ṣe pẹlu akọ̀ròyìn, Gómìnà Ganduje ní bí ọ̀rọ̀ ṣe ń fojoojúmọ́ burú síi ní ìpínlẹ̀ Kano

Ó ní kò ṣẹ̀yìn bí ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá tí Ìjọba àpapọ̀ gbé kalẹ̀ lórí àrùn apinni léèmí COVID-19 ṣe kùnà láti mójútó ọ̀rọ̀ ìpínlẹ̀ Kano.

Ó ní òun fi ọ̀rọ̀ tó àwọn aláṣẹ Ìjọba àpapọ̀ títí kan ìgbákejì Ààrẹ létí pé iná wàhálà àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí Coronavirus ń jó hèù hèù ní Ìpínlẹ̀ Kano ṣùgbọ́n kò sí ohunkóhun tí òhun rí gbọ́ padà lórí rẹ̀.

Ó ní ìyàlẹ́nu ńlá ló jẹ́ pé wọ́n ní láti ti ibùdó àyẹ̀wò kan ṣoṣo …

How my wife connived with My Deputy, Doctors while in Isolation - El Rufai

Image
"I could have died, if not for my doctors. I followed their instructions strictly and took my medications."

The Governor of Kaduna State, Mallam El Rufai has disvlised how his wives collaborated with Dr Hadiza, the Deputy Governor and seized his phones while in isolation to save his life

" I was only left with an iPad, the device I used to read and go online," the governor said

He further said; “I survived it, someone else may not know, that is why we are very serious about the disease."

“I went through trauma, even when I spoke online from isolation, I was battling with a debilitating headache. I won’t like even my enemy to suffer from coronavirus.” El Rufai revealed

He stated thst he could not exactly say how he contracted the coronavirus. But that he was in Abuja and had interacted with many people, some from overseas.

The Governor said he I was assigned to chair committees by the government. He believed it was from these interactions that he got the virus.…

Fayemi Suspends Aide over “Father Rejects Son” video:

Image
Gani SalauThe Governor of Ekiti state, Dr. Kayode Fayemi has suspended his Special Assistant on anti-gracing, Sola Durodola over the careless manner he handled the case of the father who rejected his son suspected of having coronavirus.

This was made known in a press release personally signed by the Commissioner for Information and Value orientation, Aare Muyiwa Olumilua yesterday.

The release stated that Aruwodola has been suspended indefinitely for acting outside his official duty pending the outcome of investigation into the matter.

It would be recalled that .......... who is a son to Mr Femi Adeoye smuggled himself to Ekiti State over the weekend and was refused entering into his house by Mr Adeoye and insisted that his son should be quarantined for 14 days before he could be allowed into his house.

This was done at the popular fajuyi pack as the exchange of arguments occurred between Adeoye and his son when Durodola was interviewing them as the father said he had warned his so…

Bi Olórí ẹ̀ṣọ́ Tinubu se kú iku àrùn Coronavirus

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Ikú pabírí, abírí kú, ikú pa àlàárì, ikú pa sányán baba aṣọ. Ikú kò mọ ọ̀lẹ ,bẹ́ẹ̀ ni kò wojú alágbára, ló díá fún bó ṣé síwọ́ lu olórí ẹ̀ṣọ́ aláàbò fún adarí ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Aṣíwájú Bola Ahmed Tinubu,Alhaji Lateef Raheem tó kù lẹ́yìn tó lùgbàdì àrùn apinni léèmí Coronavirus.

Tinubu fi ọ̀rọ̀ ẹ kú ara fẹ́rakù yìí léde nínú àtẹ̀jáde tí ikọ̀ ìròyìn adarí náà buwọ́lù.

Nínú àtẹ̀jáde náà ni Tinubu ti fi léde wí pé òun àti ìyàwó òun kò ní àrùn apinni léèmí Coronavirus lẹ́yìn tí àwọn ṣe àyẹ̀wò.

Adarí ẹgbẹ́ òṣèlú  APC, Aṣíwájú Bola Ahmed Tinubu ní àwọn gbé ìgbésẹ̀  láti se àyẹ̀wò náà kété tí àyẹ̀wò fi léde pé àrùn apinni léèmí Coronavirus ló pa Alhaji Raheem.

Àmọ́ wọ́n ní ọ̀kan nínú àwọn olùrànlọ́wọ́ fún Bola Tinubu ti lùgbàdì àrùn náà tó sì ti ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀.

Wọ́n fikún un pé Àjọ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ àrùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà,NCDC ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wá àwọn tí wọ́n ti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú olóògbé náà fún àyẹ̀wò árùn Coronavirus.

Ogójì ènìyàn ló ti kú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà l…

Sunday Igboho Ro Ajo ọlọ́pàá láti wá ìbejì Akeugbagold síta

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Èèkàn àwùjọ kan, Oloye Sunday Adeyemo, tí gbogbo èèyàn mọ si Sunday Igboho, ti sọ̀rọ̀ lórí ìbejì onímọ̀ kan nípa ẹṣin islam, Sheikh Taofeeq Akeugbagold, tí àwọn gende agbebọn gbé lọ lọ́jọ́ Satide. Igboho, lásìkò to ń takurọsọ pẹ̀lú àwọn akoroyin kan lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà, rawọ ẹ̀bẹ̀ sáwọn agbofinro nipinlẹ Oyo, láti ṣíṣẹ kára, fi doola ẹ̀mí àwọn ọmọdé méjèèjì náà lọ́wọ́ ewu.

Bákan náà ló tún rọ gbogbo àwọn agbófinró yíká orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, láti pawọ́ pọ̀ ṣe àwárí ìbejì ọ̀hún, kí wọ́n sì tún rí dájú pé àwọn olubi ẹ̀dá tó ṣiṣẹ́ láabi náà, fi imú kò ata òfin.Igboho ní ara Abiamọ tá òun nígbà tí òun gbọ́ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà, tó sì tún bá òun lójijì, pẹ̀lú àfikún pé, ìwà ajọ́mọgbé náà kò bójú mu rárá. Ó wá ń para pòrò pé irú àwọn ìwà ọ̀daràn báyìí kò yẹ kó máa wáyé làwọn Ìpínlẹ̀ àti orílẹ̀ èdè tí ìjọba ti ń ná owó gọbọi lórí ìpèsè ètò ààbò àti mímú àdínkù bá àwọn ìwà ọ̀daràn lóníran ǹ ran.

Ibadan Lady Advertised For Sale on Facebook by Lebanese Regains Freedom

Image
An Ibadan lady, Busari, offered for sale on Facebook by a Lebanese, Wael Jerro, has been rescued by the Federal Government of Nigeria.

The Chairman, Nigerians in Diaspora Commission, Abike Dabiri-Erewa, said on Tuesday that the victim, Busari Peace, was with the Nigerian Mission in Beirut, Lebanon.

Jerro had advertised the victim with her Nigerian passport on a Facebook page, ‘Buy and Sell in Lebanon’.

He put a price tag of $1,000 on the 30-year-old lady, Ibadan, Oyo State indigene.

The post generated outrage on the social media, as many Nigerians called for the arrest of the suspect and rescue of Busari.

Dabiri-Erewa later announced the arrest of the suspect by the Lebanese government, whom she said also condemned the act.

She assured that Busari would be rescued.

In a tweet on Tuesday accompanied by a video clip, the former house of representatives member said the victim had been rescued.

“Update on Nigerian girl put up for sale by a Lebanese, Wael Jerro, on Facebook. She has been …

Buhari Gets Acting COS As Wife Sponsors Buba Marwa

Image
By Gani SalauPresident Muhamadu Buhari has directed the General Administrative Officer, Abubakar Maikano to act as his Chief of Staff just as impeccable source revealed that the President's wife, Aisha is tipping former Lagos military Administrator, Col Buba Marwa as the substantive CoS.

The appointment of an acting COS which is an indication that President Muhammad Buhari is not in hurry to appoint a substantive CoS emerged last week in the presidency. Jostling for this vacant position started shortly after the death of former CoS, Mallam Abba Kyari died of coronavirus.

It was initially rumoured that the running mate to late MKO Abiola and the former Secretary to the Government of the Federation, Babagana Kingibe was being considered for the job. It was however learnt that Buahri's wife preferred her kinsman, former military governor of Lagos state and chieftain of the ruling All progressives congress, APC in Adamawa state, retired Brigadier General Buba Marwa.

Another sron…

Buhari Appoints 38 Persons Into Federal Character Commission's Board

Image
President Muhammadu Buhari has appointed 38 persons to the board of the Federal Character Commission (FCC).

In a letter on Tuesday, the president asked the senate to confirm the appointees.  He based his request on section 154 (1) of the constitution as amended.

Senate President Ahmad Lawan read the letter on the floor of the upper legislative chamber on Tuesday.

“In compliance with the provision of section 154 (1) of the constitution of the federal republic of Nigeria, 1999 as amended, I write to request for confirmation by the senate for 38 nominees as chairman and members of the Federal Character Commission,” the letter read.

The development is coming about two months after the senate asked Buhari to reconstitute the FCC board.

The agency has had only one commissioner out of the 37 as required by law. Abdullahi Halidu Shinkafi, the lone commissioner, has retired.

Here is a list of those newly appointed by the president:

Muheeba Dankaka, chairperson
Henry Ogbulogo
Salihu Bella
Obon…

Osun Senator Becomes Senate Spokesman

Image
The Senate President Ahmad Lawan, on Tuesday, appointed Senator Ajibola Basiru (Osun Central) as the new chairman of the Senate Committee on Media and Public Affairs.

Lawan made the new appointments at the close of plenary on Tuesday.

Senator Basiru will take over as spokesperson from the Vice Chairman Senate Committee on Media and Public Affairs, Senator Godiya Akwashiki (Nassarawa North) who has been acting as the spokesperson of the upper chamber after Senator Adedayo Adeyeye (Ekiti South) was sacked by a court from the Senate.

Senator Akwashiki is now the Chairman of the Senate Committee on Employment, Labour and Productivity formerly occupied by late Senator Benjamin Uwajumogu, while Senator Biodun Olujimi (PDP, Ekiti South) was named as the chairman of the Senate Committee on Diaspora and Non-Governmental Organisations.

It could be recalled that late Senator Rose Oko (Cross River North) chaired the Senate Diaspora Committee until her demise in March 2020.

Lawan in his closing r…

Trump, Buhari's Telephone Conversation: What They Discussed

Image
President Mohammadu Buhari in the afternoon today, Tuesday April 28, received a telephone call from his American counterpart, President Donald Trump, during which several issues were discussed.

According to a Statement released by the president's Special Adviser on Media and Publicity, Femi Adesina, the two leaders commiserated with each other on fatalities in their countries, caused by the COVID-19 pandemic.

They also shared ideas on how to successfully combat the health emergency.

President Buhari expressed condolences to the government and people of the United States over the fatalities recorded, and equally expressed worry at the high rate of deaths recorded across the world.

The associated negative impacts of the pandemic on the world’s economy also came up for discussion.

Buhari lauded Trump for the various initiatives adopted by his government to contain the further spread of the virus across the United States.

He indicated Nigeria’s readiness to cooperate with the United …

Bursary: Ekiti Students Laud Fayemi, call him 'Students' Governor' • Asks Government to increase Beneficiaries

Image
• Asks Government to increase beneficiaries


Students of Ekiti State Origin under the auspicious of the Federation of Ekiti State Students' Union (FESSU), National Body, have lauded the State Governor, Dr Kayode Fayemi on the disbursement of Bursary awards to its members.

The Union in a statement signed by its president and secretary, Akomolafe Jide and Idowu Ebenezer respectively, commended  the governor for prioritizing the satisfaction of Ekiti State indigenous students by disbursing the bursary award at this period of the ravaging Coronavirus pandemic.

"It is no gain saying that the major avenue through which the students' constituency enjoy dividends of democracy directly from the Government is via Bursary and Scholarship Awards

"However, while some of our members are thrilled on receiving payments, we note the number of qualified applicants who are not beneficiaries of the bursary awards having satisfied the requirements expected by the Ekiti State Scholarship …

Fáyemí ṣàfikún òfin kónílé-ó-gbélé, ó korò ojú sí bí wọ́n se jí Kọmíṣọ́nnà rẹ àti àwọn kan gbé

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá


Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkìtì, Ọ̀mọ̀wé Káyọ̀dé Fáyẹmí ti ṣàfikún òfin kónílé-ó-gbélé nílù ú náà pẹ̀lú ọ̀sẹ̀ kan, bẹ́ẹ̀ ló bẹnu àtẹ́ lu bí wọ́n se jí Kọmíṣọ́nnà rẹ̀ fétò ọ̀gbìn  Ọ̀gbẹ́ni Olabode Folorunso gbé.

Fáyẹmí  ṣọ̀rọ̀ yìí di mímọ̀ lásìkò tó ń jábọ̀ fún àwọn ará ìlú lórí ibi tí nǹkan dé láti ìgbà tí òfin kónílé-ó-gbélé ti bẹ̀rẹ̀.

Fáyẹmí fi àìdùnnú rẹ̀ hàn bí wọ́n jí Kọmíṣọ́nnà fún ètò ọ̀gbìn,Olóyè Folorunsho Olabode  àti àwọn mìíràn,léyìí tó mú ẹ̀mí  olórí ìjọba ìbílẹ̀ ilejemeje .
Gómìnà fi dá wọn lójú pé ìgbésẹ̀ tó yẹ tí bẹ̀rẹ̀ lórí ìṣẹ̀lẹ̀ aburú náà,nígbà tó ń rọ àwọn elétò ààbò láti sapá wọn fáàbò ẹ̀mí àwọn èèyàn náà.
Ṣaájú ní ìròyìn tí ṣọ pé wọ́n tí jí Kọmíṣọ́nnà àti àwọn èèyàn méjì nílù ú náà gbé ṣá lọ sí ibi tí ẹnikẹ́ni ò mọ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé  Kọmíṣọ́nnà ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ náà Amba Asuquo  ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé òótọ́ ni, àti pé òun ti da àwọn ikọ̀ òun síta fún àwárí wà láàyè àwọn èèyàn tí wọ́n jígbé náà.

"Mo mọ rírí ìfaradà yín fún bí i ọ̀sẹ̀  mẹ́rin sẹ́y…

COVID 19: Fayemi Extends Lockdown, Condemns Abduction of his Commissioner

Image
By Gani Salau


The Governor of Ekiti State, Dr Kayode Fayemi has extended the lockdown in the State by a week just as he condemned the abduction of his Commissioner for Agriculture, Mr Olabode Folorunso in the week.

Fayemi made this yesterday in a broadcast to the people of the state monitored in the broadcasting media within the state while reviewing the situation so far since the beginning of the knockdown in the state.

Fayemi condemned the abduction of the commissioner for Agriculture, Chief Folorunsho Olabode and others which resulted to the death of the leader of the Ilejemeje Local Council Legislative Arm and assured that the ugly incident was getting necessary action and charged the security officials to ensure their safety. It would be recalled that the commissioner and the two occupants of the vehicle were abducted over the weekend along Isan /Iye Ekiti while traveling to Iye, his home town.

"I want to acknowledge the difficult sacrifices we have all made by observing th…

Fayemi Slashes Politicians' Salaries

Image
The Governor of Ekiti, Dr Kayode Fayemi has slashed the salaries of political appointees in the State by 50%.

This was made known in a statement by the Commissioner for Information and Value Orientation, Aare Muyiwa Olumilua.

This decision, according to the release was caused consequent upon the ravaging effects of the COVID-19 scourge which made the global economy to be severely affected, with the depression affecting Nigeria as a nation, and expectedly, our dear Ekiti State.

It further read; "as a responsive and responsible government, the Fayemi-led administration has taken stock of our financial situation, vis-a-vis our constantly decreasing receipts from the federation account, as well as our dwindling internally generated revenue (IGR), and has been forced to wake up to the current realities of our fiscal position."

"With promises made to the Ekiti people while seeking their mandate, coupled with the moral duty of improving their welfare, a time for making diffic…

Atiku's Son Tests Negative For Coronavirus, 40 Days After

Image
Mohammed Atiku-Abubakar, a son of Nigeria’s former vice-president, has now tested negative for coronavirus.

“I have just received my second consecutive negative result,” Mr Atiku-Abubakar told newsmen on Monday afternoon. “My discharge is currently being processed, and I hope to be home this evening.”

The Nigerian disease control office does not comment on individual cases.

Mr Atiku-Abubakar was first confirmed to have contracted the virus on March 19 and was subsequently transferred to an isolation centre on the outskirts of the Nigerian capital, Abuja.

The 31-year-old, however, failed to test negative for the virus until today, a 40-day ordeal that experts said could be amongst the longest ever recorded in the country since the first infection was confirmed in Lagos February 27.

Coronavirus, whose latest variant COVID-19 has killed hundreds of thousands and sickened millions across the world, has an average of 14 days to run its course after infection. Most Nigerians known publicly…

Tinubu, Wife, Test For Coronavirus After Aide's Death

Image
By O’tayo Damilola Noel

National leader of All Progressives Congress, APC, Asiwaju Bola Tinubu, his wife, Oluremi have tested negative for deadly COVID-19, while his aides, tested positive.

The media aide to Tinubu, Mr Tunde Ramon, who announced this in a statement on Monday, added that the aide has been isolated in accordance with Nigeria Centre for Disease Control, NCDC, guidelines.

Recall that one of Tinubu’ s aides, the Chief Security Officer, Alhaji Lateef Raheem, who died last Friday was later tested positive for COVID-19.

The statement read in part, “Following the death of our well-respected and beloved Chief Security Officer, Alhaji Lateef Raheem, NCDC medics took the wise precaution of taking samples from his body for testing to actually determine the cause of death.

“Today, (Monday) the test results are back. The samples tested positive for COVID-19.

“As a precautionary measure taken soon after the death of Raheem, His Excellency Asiwaju Bola Tinubu, his wife, Senator Olure…

Ní Kàdúná, òfin kónílé ó gbélé yóò tẹ̀síwájú fóṣù kan

Image
By Fẹ́mi AkínṣọláÀwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí iná ò bá tán láṣọ, ó seése kí ẹjẹ wọ̀rù wọ̀rù ṣẹ́kù lórí èékánná. À ti pé, ogun tí yóó bá wọ lé kóni,  ọ̀nà la tií pàdé rẹ̀.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kàdúná ti kéde àfikún iye ọjọ́ kónílégbélé f’oṣù kàn sí i .

Gómìnà Nasir El-Rufai tó kéde ọ̀rọ̀ yìí ní ìgbésẹ náà jẹ́ ọnà àti dẹkùn àjàkálẹ̀ apinni léèmí "Covid 19" náà.

Lójú òpó abẹ́yefò Twitter rẹ ló ti sàlàyé pé níse ni òun tẹ̀lé amọran tí ìgbìmọ̀ tó n gbógun ti àrùn náà, eléyìí tí igbákejì òun ń darí fi léde.

Ní báyìí àṣẹ yìí tí f'ẹṣẹ̀ múlẹ̀ láti ọjọ́ Àìkú tí ṣe ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹrin.

Ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kẹta ní ìjọba tí ṣaájú fi Ìṣéde àkọ́kọ́ lé'lẹ̀ ni ìpínlẹ̀ ọ̀hún.

Àwọn ilé ẹjọ́ alágbèéká yóò wà níta láti dájọ́ fáwọn tó bá tasẹ̀ àgẹ̀rẹ̀ sí òfin yí .

Bẹ́ẹ̀ ni El Rufai ní àwọn yóò gbẹ́sẹ̀ lé ọkọ̀ tó bá rìn níta láì ní ìyọ̀ǹda ìjọba.

Ọ̀jọ̀gbọ́n Dibú Ọ̀jẹ́rìndé , Akọ̀wé Jánbù tẹ́lẹ̀ pàdánù ọ̀pọ̀ dúkìá sọ́wọ́ ICPC

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní iná kò mojú ẹni tó dáa, bẹ́ẹ̀ ni òfin ò mojú ẹni to gbé e kalẹ̀ bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí o, bí Ilé ẹjọ́ gíga ìlú Àbújá tí pàṣẹ pé àjọ tó ń gbógun ti ìwà ìbàjé, ICPC, gbé ẹsẹ lé àwọn dúkìá kan tó jẹ́ ti akọ̀wé tẹ́lẹ̀ fún àjọ JAMB, Ọ̀jọ̀gbọ́n Dibú Ọ̀jẹ́rìndé .

Lára àwọn dúkìá tí Ọ̀jẹ́rìndé pàdánù ṣọ́wọ́ àjọ ICPC ni iléeṣẹ́ Rédíò Gravity FM tó wà n'ilu Igboho, ilé ẹ̀kọ́ Sapati tó wà lójú ọ̀nà Ajasẹ Ipo, n'ílù ú Ilorin, ilé epo Soka tó wà n'ilu Ìbàdàn àti ilé ìtura Òkè Afin tó wà níwájú Fáṣítì ìmọ̀ ẹ̀rọ Ladoke Akintola n'ílù ú Ogbomoso.

Àwọn dúkìá yókù tí Ọ̀jẹ́rìndé yóó pàdánù ni, ilé epo àti gáàsì Doyin tó wà nílùú Ìbàdàn, ilé Tejumola tó wà ní Ikeja n'ílù ú Èkó tó fi mọ́ ilé àwòsífìlà kan tó wà lójúlé Kẹrìnlá, Yobe close, Maitama n'ílù ú Àbújá pẹ̀lú dúkìá rẹ̀ míràn tó wà ní orílẹ̀ èdè South Africa.

Kódà, Ọ̀jẹ́rìndé tún pàdánù àwọn ìpín Ìdókòwò àti owó tó níkìmí tó ní láwọn ilé ìfowópamọ́sí sí ọwọ́ àjọ ICPC.

Ìkéde nípa àwọn dú…

Ṣé lóòtọ ni àwọn agùnbánirọ̀ kò ní gba owó oṣù kẹrin àti ìkaàrún?

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ọ̀rọ̀ òkèèrè bí ò lé kan, a dín kan. Èyí ló mú kí ajọ àgùnbánirọ̀ lórìlẹ-èdè Nàìjíríà (NYCS) kéde pé àwọn yóò san owó oṣù Kẹrin àti ìkaàrún fún wọ́n láì mú ìwé tí wọ́n ń buwọ́lù lósoosù wá. láti fòpin sí wọ́n ní wọ́n pé , tí àwọn èèyàn kan ń gbé kiri.

Nínú àtẹ̀jáde kan ti adarí ìròyìn àjọ náà Adenike Adeyemi buwọ́lù ló ti sàlàyé pé wọn kò nílò láti buwọ́lu iwé kankan kí wọ́n tó gba owó ti osù kẹrin àti ìkaàrún ọdún 2020.

Ó ní àtẹjáde yìí wáyé nítori ìròyìn òfegè tó ń tàn ká pé adarí àjọ NYSC sọ pé owó oṣù kẹrin àti ìkaàrún kò ní tẹ àwọn àgùnbánirọ̀ lọ́wọ́ nítorí wọ́n yóò lòó láti gbógun ti àrùn apinni léèmí Covid 19.

IMOLITES, COVID-19 Is Now In Our State - By Dr. Achigbu Kingsley

Image
Good morning Management and Staff of our dear Centre. There is a need to address us this morning on the events of the past 24hours. We woke up in the early hours of yesterday 25th April, 2020 to the  obvious reality that COVID-19 is no respecter of physical boundaries as the first positive and confirmed case was identified in Owerri, Imo state.

He is a 45year old man who lives and works in Owerri and is not a staff of the Centre as may be widely speculated. He was promptly admitted into the Isolation facility. He is presently not showing symptoms and is on appropriate management based on the NCDC guidelines. The facility is equipped to handle his case.

The essence of this briefing is for us to show more vigilance as well as fully abide by recommended preventive measures such as; frequent hand washing with soap and water,  use of alcohol based sanitizers, maintaining appropriate social distancing, avoidance of crowding, consistent wearing of face masks which we have provided for staff…

COVID-19: Two Patients Flee After Testing Positive in Borno

Image
Officials have claimed that A man and woman in Borno State are currently on the run after they had tested positive for COVID-19.

The Borno commissioner of health, Salisu Kwayabura, disclosed this information to journalists at the daily briefing of the Committee on COVID-19.

He said, “two patients, Abbas Kaka Hassan, a 24-year-old male and Hauwa Mohammed, 42-year-old female, are on the run after testing positive to COVID-19 at the University of Maiduguri Teaching Hospital in the metropolis.”

He said the male is from Layin tanki suburbs in Gwange II ward, while the woman lives in the Shuwari ward.

It was gathered that the male patient could earlier not be reached by the state COVID-19 response team even after his blood sample was collected. He later reportedly switched off his phone.

“When samples of patients with contacts to index cases are collected, they are normally advised to go on self-isolation,” the health commissioner said.

“They give their contacts so they can be reached when…

Eeyan Keji Ku Nitori Korona l'Ọ̀yọ́

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Ikú kìí se ẹgbẹ́ àrùn o. Àrùn ló se é wò,a ò rí ti  ọlọ́jọ́ se.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́  ti kéde pé ó ti di ẹni méjì tó kú báyìí nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus ní ìpínlẹ̀ náà.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , onímọ Ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé  ló kéde rẹ̀ lórí ẹ̀rọ  ìkànnì abẹ́yefò Twitter ní Ọjọ́ Àìkú.

Gómìnà náà ní ẹni tókú náà wà lára àwọn tí àyẹ̀wò ṣẹṣẹ fihàn pé wọ́n ní àrùn apinni léèmí Coronavirus.

Bẹ́ẹ̀ ni Gómìnà náà fikún un pé ènìyàn mọ́kànlélógún ló ti ní àrùn náà nípìńlẹ̀ náà, àmọ́ ènìyàn mẹ́jọ nínú wọn ló ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́lọ́wọ́.

Oyo Records Second Coronavirus Death

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Oyo State has recorded its second coronavirus death.

 Oyo State Governor,Engineer  Seyi Makinde made this known on Sunday via a post on Twitter.

The governor stated that the victim was one of the three coronavirus cases confirmed in the state yesterday.

 “Sadly, one of the new COVID-19 cases announced yesterday, passed away this morning. This brings the number of COVID-19 related deaths in the state to two. So, there are currently eight active cases in Oyo State.” He said


If you have Yoruba news for us, contact us by calling or sending to: +234 805 613 2050

Àwọn ajínigbé tí palẹ̀mọ́ àwọn ìbejì Ààfáà àgbà oníwáàsí Sheikh Taofeeq Akeugbagold

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá

Àwọn kọ̀lọ̀rànsí ẹ̀dá kan tí ẹnikẹ́ni ò lè sàpèjúwe wọn tí palẹ̀ àwọn ìbejì Ààfáà àgbà oníwáàsí n nì Sheikh Taofeeq Akeugbagold mọ́ ó. Ààfáà àgbà náà ló fí ọ̀rọ̀ yìí léde lójú òpó abánidọ́rẹ̀ẹ́  síwèé wojú( Facebook) . Pé ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà pàtì náà wáyé ní nǹkan bí aago mẹ́jọ àṣálẹ́  ọjọ́ Àbámẹ́ta tí òǹkà ààwẹ̀ di méjì. Ó tẹ̀síwájú pé nǹkan bíi Ìṣẹ́jú mẹ́wàá tí òun tí rékọjá sí ibi tí òun ó ti sètò wáàsí ni  àjálù náà wáyé.

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó tí fi ọ̀rọ̀ náà tó ilé iṣẹ ọlọ́pàá létí, síbẹ̀, ó ní àánú ló ń bèèrè fún . Kí gbogbo ìlú o máa gbàdúrà fún òun kí àwọn tó ṣiṣẹ́ náà síjú àánú wo òun , kí wọ́n yááfi  òun fún Ọlọ́run  nínú oṣù tí a wà yìí.
Ó ní kí wọ́n wò tí ìyá àwọn ọmọ òun náà tó ṣé pé ipò àgàn ló wà fún odidi ọdún méjìlá kí àánú Ọlọ́run tó ṣokùnfà bí a ṣé rí ọmọ bí.
Ní báyìí, ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí fìdí ìṣẹ̀lẹ̀ náà múlẹ̀, lẹ nígbà tí ó ń bá akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀.
Ọ̀gbẹ́ni Olugbenga Fadeyi ṣọ pé ọwọ́ ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá tí tẹ àwọn afurasí kàn lórí ìṣẹ̀lẹ̀ n…

Fountain Newsbreaker to Publish News in Yoruba Language

Image
In a move to encourage the use of our local language and to promote knowledge of the Yoruba language, we at Fountain Newsbreaker will henceforth be publishing Yoruba news.

This will be handled and edited by our Assistant Editor, Akinfemi Akinsola. We are however calling on anyone who has Yoruba news to submit to us for publication by contactacting him (Akinfemi) on +2348056132050

Two Die of Coronavirus in Osun State

Image
Osun state Governor Adegboyega Oyetola has confirmed the death of two coronavirus patients. Oyetola disclosed this on Sunday during a briefing. He said the two fatalities were male who had underlying health conditions.
The Governor warned residents across the state against bringing in visitors from outside the state, blaming that compromise has made the state record 12 more new cases. Governor Oyetola said “the State of Osun made significant progress in the fight against coronavirus in two weeks, having no new confirmed cases and discharging 19 of the 20 successfully without any death. We were on our way to containing the virus, in spite of the galloping figures in other states. “However, it is saddening that we have recorded 12 new cases in the State, including three of our health workers with two fatalities, both of whom were males with underlying health conditions”.
Speaking more about the locations of the fresh confirmed cases, Oyetola said that the cases emerged from Ede, Irewole, Ejig…

The Truth About COVID-19 in Nigeria - By Ebun Adegboruwa, SAN

Image
By Ebun Adegboruwa, SAN
Yesterday, a friend called me that he was having difficulty breathing, he’s been weak and has pains in the heart.

I immediately told him to race to Landmark isolation Centre in Oniru, Victoria Island, Lagos. He went there straight but was turned back, as he was told that it’s only meant for those who have tested positive already. I encouraged him to wait till day break so he could go to Yaba, the main COVID 19 center in Lagos.

On reaching out to Yaba, he was told to describe his symptoms on record by way of sms and send it. In response, he was told that he could not be tested this week again as they are already booked for this week. He will be programmed for next week for his test. So, what happens to him between now and next week?

A similar situation was reported in Ajah early this week. They called NCDC in Lagos and they kept postponing the test. By the time NCDC officers got to Ajah the man had died and the family resisted them from carrying the corpse.

So,…

On Abducted Commissioner... - Ekiti Govt

Image
The Ekiti state commissioner for Agriculture, Folorunsho Olabode, was kidnapped yesterday, Sunday, 26th of April, 2020. The kidnappers also shot dead the councillor of Ilejemeje local government area of the state who was with him. The incident reportedly took place between Isan and Iludun-Ekiti. In reactions to the incident, Are Muyiwa Olumilua, commissioner for information and values orientation in Ekiti State, confirming the incident, said a security team was on the trail of the kidnappers. “The Government of Ekiti State hereby  confirms the abduction of the Honorable Commissioner for Agriculture, Chief Folorunso Olabode, by suspected bandits at about 7:00pm on Sunday April 26, 2020 on his way from Ado-Ekiti to his hometown in Iye-Ekiti, Ilejemeje LGA of Ekiti State”.

“From initial reports, the kidnappers shot one person in his entourage, the driver of the vehicle, a serving Councillor, in the ensuing fracas”

“Governor Kayode Fayemi has mandated the security agencies in the State t…

Varsity Dons Invent COVID-19 Herb

Image
Some  scientists at the University of Ibadan have recommended a plant called Euphorbia Hirta as a herbal alternative to mitigating some of the diseases associated with the COVID-19 pandemic.

According to the scientists, some of the diseases, which the plant can cure, include dry cough, respiratory failures and fever, among others. The scientists, including Profs. Ademola Ladele and Rasheed Awodoyin, told the News Agency of Nigeria (NAN) in Ibadan on Tuesday that the Euphorbia Hirta was commonly called Asthma plant.

Awodoyin, a Weed Ecologist, said that the plant was known as Asin Uloko in Edo, Nonon Kurciya in Hausa, Chamma Chamma in Kanuri, Endamyel in Fula-Fulfulde (Borno), Ba Ala in Owerri and Akun Esan in Yoruba.
He listed the scientists who worked on the plant to include Prof. Olaniyi Babayemi (Animal Scientist), Prof. Olapeju Aiyelaagbe (Chemist), Dr Ahmed Abu (Animal Scientist), Dr Adeoluwa (Organic Agriculturist), Dr Olajumoke Fayinminnu (Toxicologist) and Dr Funmilayo Adebiy…

Ekiti LG Boss Seals off Borders Till Further Notice

Image
The Chairman of Ekiti west Local Government, Hon Kareem Agunbiade on Saturday Sealed off  the boundaries linking Ekiti State through Ekiti west Local Government.

This, according to him was in line with the directive of the Governor Dr. John Kayode Fayemi that all southwest Governors had agreed to close all their borders and impose restriction of interstate movement to curb the spread of COVID-19 in the region.

Agunbiade who led the team of Ekiti west Local Government COVID-19 Task force to implement the order, urged law enforcement agents to adhere strictly to the implementation of the order.

 The Chairman and other members of the task force which comprised of the Vice Chairman to the Local Government, Alhaja Motunrayo Adesina, Security Agents, Local Government Health Workers, Leader of the legislative arm of the Council and other members went round the borders to Ekiti State through Okemesi ekiti  and Osun State boundaries.

Agunbiade in his statement, assured the people of Ekiti wes…

Tinubu Mourns Late Aide, says; Lateef Raheem, My Extraordinary Aide

Image
A good and decent man has gone. My Chief Security Officer, Alhaji Lateef Raheem, has passed and his death cuts severely. Lateef reported for work on Monday. Feeling a bit under the weather, he went home to rest. We spoke on Wednesday by phone. He was in fine spirits and was looking forward to resuming work. I felt nothing but profound shock, and then the emptiness of deep loss when I was awakened early Friday that my most trusted security aide had died and that I would never see him again. I did not know the Wednesday conversation would be our last. The pain of his loss is acute.

Lateef passed away during the early morning of Friday, April 25. He was buried later that day in accordance with Muslim rites. He was 51. His unexpected death apparently was due to complications from diabetes and high blood pressure. Lateef was a person of strong and resilient character. He never sought special treatment or favor despite his years of loyal and excellent service to me. He never took his work …